You are currently viewing Start Lyrics – Asake
Via - BellaNaija

Start Lyrics – Asake

Start Lyrics

[Intro: Aṣa]
Ojúmọ́ ti mọ́
Ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́
Ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o

[Verse: Asake]
Mr. Money steady killing show
Anywhere me I enter it’s a big intro
Ọtọ la wa, kogba gidigbo
Street orientation as ọmọ iko
Pa-pa-ranpa, pa-pa-ranpa
Ba se n gbọ Afro-beat la n Calypso
Original boy from Lungu to space
New sound I’m feeling cool
Me I wan free my mind, make I no yarn too much
Elevate my mind make, I no talk too much
Oh God, I’m praying, Abba father, give me more life
Woah, woah, woah, woah, woah, woah, woah, thug life

Artist – Asake

Release Date on Aug. 9, 2024

Album – Lungu Boy