Wow Lyrics, Militerian Lyrics,Soapy Lyrics ,Sweet in the Middle Lyrics,,Money on the RoadPuta Lyrics, Lyrics,Marry Juana Lyrics,

Soapy Lyrics – Naira Marley

Soapy Lyrics

[Intro]
Ó t’esè lé èfó
Yahoo ni babaláwo (Yawo ni babaláwo)
Olè l’everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
(Bàráwò, bàráwò, bàráwò)
Mó bá ṣá ni bàráwò

[Verse 1]
Ó t’esè lé èfó (Ó t’esè lé èfó)
Yawo ni babaláwo (Yawo ni babaláwo)
Olè l’everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
Ó fé ṣè’kà fún mi (Ófé ṣè’kà fún mi)
Mi ò l’ógùn mo ní Kùránì (Mo ní Kùránì)
Mo dè ń ṣ’àdúrà mi
Bí n sé ń ṣ’àdúrà mi, Allah ń gbà’dúrà mi (Allah ń gbà’dúrà mi)
A ti lo a ti dé (A ti lo a ti dé)
Eni orí yo ó dilé (Eni orí yo ó dilé)
Ení ba lo l’ó ba dé
Ìgbà tí n padà dé ń’ṣe l’ón dé mi l’ádé (Ń’ṣe l’ón dé mi l’ádé)
K’ádé k’ó pé l’órí (K’ádé k’ó pé l’órí)
Kí bàtà k’ó pé l’ésè (Kí bàtà k’ó pé l’ésè)
K’àwon òtá mi kán l’ésè
K’àwon [?] [?] kí wón kán l’ésè
[Bridge]
Inside life, l’oó ti rí Five Alive (L’oó ti rí Five Alive)
Inside life, l’oó ti rí Deeper Life (L’oó ti rí Deeper Life)
Inside life àwon kan ń jè’yà, àwon kan ń chop life (Inside life)
Inside life àwon kan ń ṣ’épè, àwon kan ń j’èwà

ALSO READ  Giddem Lyrics - Naira Marley

[Chorus]
Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison ń jó soapy (Ìkòyí prison ń jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy)
Jó soapy
T’ó ò bá ní’yàwó ń’lé k’o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t’o bá lo ń soapy (Soapy)

[Verse 2]
Ṣ’o d’ówó mò (Ṣ’o d’ówó mò)
Owá so pé òmo Naira (Owá so pé òmo Naira)
Ówúwo l’ówó, ìwo ṣáà ṣe sí Naira (Ìwo ṣáà ṣe sí Naira)
Ajá fé dè’nà d’ekùn
Kékeré ekùn ò mà ń ṣ’egbé ajá (Kò ń s’egbé ajá)
Wón ń bé ni, má fòó, àwon náà ò fé wàhálà (Àwon náà ò fé wàhálà)
I just want make mama proud (I just want make mama proud)
They want to make mama cry (They want to make mama cry)
Mama, you gonna cry no more
T’e bá sun’kún gan, e ó so’kún ayò (E ó so’kún ayò)
Tí n bá ń jó k’e bá n yò (K’e bá n yò)
K’órò mí já s’áyò (K’órò mí já s’áyò)
Inside life (Inside life)
Kú àwon ’cause it’s my life (Kú’òn’bè!)
[Bridge]
Inside life, l’oó ti rí Five Alive (L’oó ti rí Five Alive)
Inside life, l’oó ti rí Deeper Life (L’oó ti rí Deeper Life)
Inside life àwon kan ń jè’yà, àwon kan ń chop life (Inside life)
Inside life àwon kan ń ṣ’épè, àwon kan ń j’èwà

ALSO READ  Brain Damage Lyrics - Pink Floyd

[Chorus]
Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison ń jó soapy (Ìkòyí prison ń jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy)
Jó soapy
T’ó ò bá ní’yàwó ń’lé k’o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t’o bá lo ń soapy (Soapy)

Artist – Naira Marley

Release Date on Jun. 28, 2019